147 Protogeneia
147 Protogeneia jẹ́ ìgbàjá tó fẹ̀ nínú àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré tí Lipót Schulhof tí ó jẹ́ onímọ̀ ìràwọ̀ ọmọ orílẹ̀ èdè Hungary ṣàwárí rẹ̀ ní Ọjọ́ kẹwá Oṣù keje ọdún lati ìwòràwọ̀ tí ó ̣se lati Vienna; Èyí nìkan ni àwárí tí ó ṣe nínú àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré. Orúkọ rẹ̀ jẹ́ Gríkì tí ó túmọ̀ sí "Àkọ́bí", Karl L. Littrow ló mú orúkọ yìí nítorí èyí jẹ́ ìsọ̀gbé oòrùn kékeré àkọ́kọ́ tí onímọ̀ ìràwọ̀ tí wọ́n ti mọ̀ tẹ́lẹ̀ sí iṣẹ́ míràn nínú ẹ̀ka ìtòràwọ̀.
A three-dimensional model of 147 Protogeneia based on its light curve |
|
Ìkọ́kọ́wárí[1] and designation
| |
---|---|
Kíkọ́kọ́wárí látọwọ́ | Lipót Schulhof |
Ọjọ́ ìkọ́kọ́wárí | 10 July 1875 |
Ìfúnlọ́rúkọ
| |
Sísọlọ́rúkọ fún | Protogeneia |
Minor planet category |
Main belt |
Àsìkò 31 July 2016 (JD 2457600.5) | |
Aphelion | 3.2230 AU (482.15 Gm) |
Perihelion | 3.04727 AU (455.865 Gm) |
Semi-major axis | 3.13512 AU (469.007 Gm) |
Eccentricity | 0.028020 |
Àsìkò ìgbàyípo | 5.55 yr (2027.6 d) |
Average orbital speed | 16.82 km/s |
Mean anomaly | 92.9051° |
Inclination | 1.9309° |
Longitude of ascending node | 248.357° |
Argument of perihelion | 100.692° |
Iyeìdáméjì ìfẹ̀kiri | 66.465±2.55 km 59.22 ± 5.225 km |
Àkójọ | (1.23 ± 0.05) × 1019 kg |
Iyeìdáméjì ìṣùpọ̀ | 14.13 ± 3.78 g/cm3> |
Equatorial surface gravity | 0.0371 m/s² |
Equatorial escape velocity | 0.0703 km/s |
Rotation period | 7.8528 h (0.32720 d) |
Geometric albedo | 0.0492±0.004 |
Ìgbónásí | ~157 K |
Spectral type | C |
Apparent magnitude | 12.4 to 14.5 |
Absolute magnitude (H) | 8.27 8.8 |
Àwọn ìtọ́kasi
àtúnṣe
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |