Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2000
(Àtúnjúwe láti 2000 Summer Olympics)
Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Oru 2000 lonibise bi Awon Idije Olimpiadi
Fáìlì:Sydney 2000 Logo.svg | |
Ìlú agbàlejò | Sydney, Australia |
---|---|
Motto | Thousands of hearts with one goal Share the Spirit Dare to Dream |
Iye àwọn orílẹ̀-èdè akópa | 200 |
Iye àwọn eléré ìdárayá akópa | 10,651 (6,582 men, 4,069 women) |
Iye àwọn ìdíje | 300 in 28 sports |
Àjọyọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ | 15 September |
Àjọyọ̀ ìparí | 1 October |
Ẹni tó ṣíi | Governor-General Sir William Deane |
Ìbúra eléré ìdárayá | Rechelle Hawkes |
Ìbúra Adájọ́ | Peter Kerr |
Ògùnṣọ̀ Òlímpíkì | Cathy Freeman |
Pápá Ìṣeré | Stadium Australia |