2007 floods of Africa je eyi ti ajo UN jabo iroyin pe o je agbara to lewu ju lo ninu itan. Àgbàrá naa bere pelu òjò ni September 14, 2007. Orile-ede to le ni merinla ni agbaye Africa ni agbara yi ti pa la ra,awon eniyan 250 ni won jabo iroyin wi pe won ti ku sinu agbara yi, o si ti pa eniyan 1.5 million lara. Ijo igbimo UN ti se ikilo aarun inu omi ati kokoro ti o maa n fa ewu fun ago ara eniyan.

Iroyin lati orisun African àtúnṣe

Ghana àtúnṣe

Eniyan 400,000 ni Ko ni ile Lori Mo pelu Ogun eniyan o Kerr ju ni o ti do ku ati ohun Ogbin ati awon nkan sin sin ni won ti ba Agbara lo. Àdàkọ:Cquote[1]

George Azi Amoo - Ghana's national disaster management co-ordinator

Sudan àtúnṣe

Awon eniyan 64 ni won jabo iroyin wi pe won ti di oku.

Ethiopia àtúnṣe

Eniyan metadinlogun ni won ti di oku Ninu iroyin. Ni Afar Region,agbara ojo Awash River fa iparun dam. Bi eniyan 4,500 ni won ta ku si ona ti omi si yi won ka.

Uganda àtúnṣe

Eniyan 150,000 ni won sonu ti awon eniyan ookanlelogun si ti di oku. Ile iwe 170 ni o si wa ni abe omi.

Rwanda àtúnṣe

Awon eniyan mejidinlogun ti di oku,ile 500 si ti ba agbara lo.

Mali àtúnṣe

Afárá Marun ti parun bee si ni agbara ti wo ile 250 lo.

Burkina Faso àtúnṣe

Eniyan 33 ni iroyin jabo pe won ti di oku

Kenya àtúnṣe

Eniyan mejila ti di oku.

Togo àtúnṣe

Ogun eniyan ni o ti di oku.

See also àtúnṣe

Awon itokasi àtúnṣe

External links àtúnṣe