2008 Namibia Floods
Àgbàrà omi Nàmíbíà ti ọdún 2008 wáyé ní ìbẹ̀rẹ̀ Fẹ̀búárì 2008, èyí tí ó fa àgbàrà òjò nla fún bii Àádọ́ta ọdún..[1] Àgbàrá òjò náà pa ènìyàn tó ń lọ bíi méjìleníaadorin ní ìbẹ̀rẹ̀ oṣù kẹta,[2]pẹ̀lú àpàpọ̀̀ èniyàn tó lé ní 65,000 tí wón farapa, ní àgbègbè Omusati, Oshikoto, Oshana, Ohangwena àti Çarpıcı.[3] Namibia Red Cross ran bí Ọ̀ọ́gọ̀rín ènìyàn lówó.[4] Èrò lapoju àti àìní ìmọ́tótó ló fa aìmójútó ní Káàmpù.[5]
Ọ̀gọ̀rọ̀ èniyàn tó wà ní kám̀pú náà ṣàkóbá bá ètò-ìlera ní ibẹ̀,[3][6] ìtànkálẹ̀ àrùn ibà sì wáyé, èyí tí wọ́n kéde ní oṣụ̀ kẹta.[6] Ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹta, àjọ United Nations Office for Outer Space Affairs ké sí International Charter for "Space and Major Disasters".[7]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Hooli, Lauri Johannes (2016). "Resilience of the poorest: coping strategies and indigenous knowledge of living with the floods in Northern Namibia" (in en). Regional Environmental Change 16 (3): 695–707. doi:10.1007/s10113-015-0782-5. ISSN 1436-3798.
- ↑ "Floods in Namibia kill 42 and displace thousands" (in en). Reuters. 2008-03-04. https://www.reuters.com/article/us-namibia-floods-idUSL0437637720080304.
- ↑ 3.0 3.1 Namibian, The. "65 000 affected by floods". The Namibian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-11-21. Retrieved 2019-10-23.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:10
- ↑ "After devastating floods, Namibians fight cholera and wait for a return to normalcy". UNICEF. Archived from the original on 2019-10-18. Retrieved 2019-10-24.
- ↑ 6.0 6.1 Sibeene, P. (2008) Namibia: Cholera Outbreak in North. All Africa. March 11. [online] Last accessed 18/10/19. Available at https://allafrica.com/stories/200803110236.html
- ↑ United Nations Response to Combat Floods in Namibia United Nations Information Service, 14 March 2008