2009 Angola, Namibia and Zambia floods
2009 Angola, Namibia and Zambia floods jẹ́ ì
ṣẹ̀lẹ̀ ìparun tí ó wáyé ní ìṣẹ̀sẹ̀ bẹ̀re oṣù kẹta ọdún 2009 tí ó sì yọrí sí ikú àwọn tí ó tó ọkàn lè láàdóje tí ó sì tún pa àwọn tí ó tó 445,000 pe.[1]
Ìṣẹ̀lẹ̀ ìkún omi yìí pa ẹ̀yà méje ìlú Namibia lára, ìsòrí mẹ́ta láti Zambia, méjì láti Angola àti apá àwọn ibì kan ní Botswana. Ìṣẹ̀lẹ̀ ìkún omi yìí wó ilé àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ibùgbé tí ó sọ àwọn ènìyàn tí ó tọ́ 300,000 di aílà ní ilé lórí. Ìjọba sì kéde àkíyèsi pàjáwìrì ní apá ìwà ọrùn-ùn Namibia tí ìpayà sí wà pé àrùn àjàkálè léè bẹ́ kalẹ̀ ní ìlú yìí.[2]
Àjọ Red cross àti àwọn ìjọba yòókù, wọ́n sì ràn wọ́n lọ́wọ́.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Namibia flood disaster". The Times (South Africa). 19 March 2009. Archived from the original on 25 March 2009. https://web.archive.org/web/20090325081652/http://www.thetimes.co.za/News/Article.aspx?id=962726. Retrieved 20 March 2009.
- ↑ "Floods hit Angola-Namibia border". BBC. 13 March 2009. Archived from the original on 16 March 2009. https://web.archive.org/web/20090316073624/http://news.bbc.co.uk/2/hi/africa/7941255.stm. Retrieved 20 March 2009.