2023 ní Nàìjíríà
Àtòjọ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ 2023 ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀
àtúnṣe- Ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì(Feb 25) – Ìdìbò Gbogbogbòò Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà àti sílé ìgbìmọ̀ aṣòfin wáyé, Bola Ahmed Tinubu ni ó jáwé olúborí nínú ìdìbò ààrẹ.[1][2]
- Ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹta(March 18)– Ìdìbọ̀ sípò àwọn Gomina Nàìjíríà àti Ilé ìgbìmò aṣòfin àwọn Ìpínlẹ̀ ti ọdun 2023 wáyé.[3]
Ọ tún le ka
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "JUST IN: INEC Sets New Dates for 2023 General Elections". February 26, 2022. Archived from the original on January 13, 2023. Retrieved February 16, 2023. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "BREAKING: INEC declares Tinubu winner of presidential election". Punch Newspapers. 2023-03-01. Retrieved 2023-03-01.
- ↑ "Breaking: INEC Shifts Governorship, Assembly Elections to March 18 – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE – Truth and Reason. 2023-03-09. Retrieved 2023-03-18.