Curtis James Jackson III (ọjọ́ ìbí Oṣù Kéje 6, 1975), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ 50 Cent, jẹ́ ará Amẹ́ríkà rapper, olùtajà, olùdókòòwò, atọ́kùn àwo orin, àti òsèré. Ó gbajúmọ̀ lẹ́yìn ìgbà tí àwọn àwo rẹ̀ "Get Rich or Die Tryin'" (2003) ati "The Massacre" (2005) jade. "Get Rich or Die Tryin'" ti gba ìwé-ẹ̀rí platinum mẹ́jọ láti ọwọ́ RIAA.[1] Àwo rẹ̀ "The Massacre" gba ìwé-ẹ̀rí platinum máàrún láàtı ọwọ́ RIAA.[1]

50 Cent
50 Cent at the 2009 American Music Awards
50 Cent at the 2009 American Music Awards
Background information
Orúkọ àbísọCurtis James Jackson III
Ọjọ́ìbíOṣù Keje 6, 1975 (1975-07-06) (ọmọ ọdún 46)
Ìbẹ̀rẹ̀South Jamaica, Queens, New York, I.A.A.
Irú orinHip hop
Occupation(s)Rapper
Years active1997–present
LabelsShady, Aftermath, Interscope
Associated actsG-Unit, Dr. Dre, Eminem, Sha Money XL
Website50cent.comÀwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe