Ahéré

(Àtúnjúwe láti Aáré)

Aáré jẹ́ ilé ìgbẹ́ kékeré kan, tí wọ́n fi Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ohun-èlò ṣe. Aáré jẹ́ ilé tí àwọn ènìyàn mìíràn rí gẹ́gẹ́ bíi ilé àìtọ́ fún àwọn tó máa ń ya ètò ilé nítorí wí pé wọ́n máa ń lo àwọn ohun èlò tó n wà tẹ́lẹ̀ bíi igi, òkúta, koríko, igi ọ̀pẹ, ara igi àti amọ̀ ní lílo àwọn ọ̀nà tí wọ́n ń lò láyé àtijọ́

A home in rural area in Cross River State 6

.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Oxford English Dictionary Second Edition on CD-ROM (v. 4.0) © Oxford University Press 2009