Aïcha Elhadj Macky (8 Oṣù Kínní Ọdún 1982) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nìjẹ̀r. Ó tún jẹ́ onímọ̀ nípa àwùjọ.[1] Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún dídarí eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Fruitless Tree.[2]

Aïcha Macky
Ọjọ́ìbíAïcha Elhadj Macky
8 Oṣù Kínní 1982 (1982-01-08) (ọmọ ọdún 42)
Niger
Orílẹ̀-èdèNigerien
Iléẹ̀kọ́ gígaGaston Berger University
Iṣẹ́Director
Ìgbà iṣẹ́2011–present

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Macky, Aicha: Sociologist and Filmmaker, Niger Republic". amesall. Archived from the original on 20 October 2020. Retrieved 11 October 2020. 
  2. "The Fruitless Tree / a film by Aicha Macky.". African Filmny. Retrieved 11 October 2020. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

àtúnṣe