Aldehyde dehydrogenase 1 family, member A3, tí a tún mọ̀ sí ALDH1A3 tàbí retinaldehyde dehydrogenase 3 (RALDH3), jẹ́ enzyme nínú àwọn ènìyàn tí  ALDH1A3 gene, ń kóòdù fún[1]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Aldehyde dehydrogenase isozymes jẹ́ àwọn enzymes tí a rò wípé wọ́n ń ṣiṣẹ́ takuntakun ní pípa oró àwọn aldehyde tí ó jẹyọ nínú ètò ògógóró àti ìtúká lipid nínú ara. Àwọn enzyme tí ó ń kóòdù fún gene yìí máa ń lo retinal gẹ́gẹ́ bí ohun ìbẹ̀rẹ̀, yálà lọ́fẹ́ tàbí retinal tí ó tòrò mọ́ protein nínú sẹ́ẹ̀lì.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Molecular cloning, genomic organization, and chromosomal localization of an additional human aldehyde dehydrogenase gene, ALDH6". Genomics 24 (2): 333–41. November 1994. doi:10.1006/geno.1994.1624. PMID 7698756. 
  2. "Entrez Gene: ALDH1A3". 

Ìwé àkàsíwájú síi

àtúnṣe