Abímbólá Adelakun
Abímbọ́lá Adélakùn Abímbọ́lá Àdùnní Adélakùn ( ọjọ́ ìbí 15 September[ọdún?]) Ó jẹ́ ọ̀nkọ̀wé Nàìjíríà. Ìgbésí ayé A bíi ní ìlú Ìbàdàn, SouthWest Nàìjírià, Ó kẹ́kọ̀ọ́ ní University of Ibadan, níbití ó tí jáde pẹlú bachelor's degree àti Master of Arts degree in communication and language arts.Ó jáde pẹlú Ph.D. nínú ijó and eré orí ìtàgé ní University of Texas, Austin.[1] Ó ṣiṣé pẹlú The Punch newspaper ní ìlú Èkó, Nàìjírià, gẹ́gẹ́bí ọ̀ǹkọ̀wé. Ó ṣiṣẹ́ pẹlú The Punch newspaper ní, Nàìjírià, gẹ́gẹ́bí Òǹkòwé. Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa modern African culture bí wọ́n ṣe ń gbé àti ṣíṣe through the disciplinary lenses of performance, gender, Africana, and Yoruba studies. Ó kọ oríṣiríṣi ìwé ẹ̀kọ́ tí wọ́n ti tẹ̀ jáde ní oríṣiríṣi journals pẹlú Journal of Women and Religion, and Journal of Culture and African Women Studies. Lára àwọn ìṣe rẹ̀ ni ‘Coming to America: Race, Class, Nationality and Mobility in “African” hip hop’ 2013; Pentecostal Panopticism and the Phantasm of “The Ultimate Power” 2018; ‘The Spirit Names the Child: Pentecostal Names and Trans-ethics’ 2020; ‘Black Lives Matter! Nigerian Lives Matter!: Language and Why Black Performance Matters’ 2019; ‘Pastocracy: Performing Pentecostal politics in Africa’ 2018; ‘Godmentality: Pentecostalism as performance in Nigeria’ 2017; ‘The Ghosts of Performance Past: Theatre, Gender, Religion and Cultural Memory’ 2017; ‘Spectacular Prophecies: Examining Pentecostal Power in Africa’ 2017; ‘Remixing Religion: An Interdisciplinary Graduate Student Conference’ 2014; ‘Yoruba Studies Review’ and ‘I am hated, therefore I am: The Enemy in Yorùbá Imaginary’[2][3]
Òun ni Òǹkòwé Under the Brown Rusted Roofs.[4] Ìtọ́kasí ^https://liberalarts.utexas.edu/aads/faculty/aaa3475 ^ https://scholar.google.com/citations?user=4Z0JYQ0AAAAJ&hl=en ^http://independent.academia.edu/AbimbolaAdelakun/CurriculumVitae ^ "A gleam of Nigerian literature online". The Nation. Archived from the original on 2011-03-26. Retrieved 2009-11-21. External links Under The Brown Rusted Roofs - review in Saraba Magazine[permanent dead link] Nigerian writers' tour starts on a good note - Guardian[dead link]
This article about a Nigerian writer or poet is a stub. You can help Wikipedia by expanding it. Last edited on 29 September 2020, at 20:38
Content is available under CC BY-SA 3.0 unless otherwise noted. Privacy policy Terms of Use Desktop HomeRandomNearbyLog inSettingsDonateAbout WikipediaDisclaimers LanguageWatchEdit