Abọ́bakú ni eré oníṣẹ́ agbéléwò kan tí Femi Odugbemi ṣe akọsílẹ̀ rẹ̀ tí Niji Àlàmú sì darí rẹ̀ bákan náà.[2] Eré náà gba amì-ẹ̀yẹ Most Outstanding Short Film ní ibi ayẹyẹ Zuma Film Festival àti Best Costume tí wọ́n ṣe ní ibi ayẹyẹ 6th Africa Movie Academy Awards ní ọdún 2010. Àwọn ayẹyẹ yí ni wọ́n wáyé ní ìlú YenagoaÌpínlẹ̀ Bayelsa ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2010.[3][4]

Abọ́bakú
AdaríNiji Akanni
Olùgbékalẹ̀Femi Odugbemi
Òǹkọ̀wéDapo Olawale [1]
Ìyàwòrán sinimáNiji Akanni
Ilé-iṣẹ́ fíìmùDVWORX Studio
Déètì àgbéjáde2010
Àkókò35 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèYoruba and subtitled in English

Àwọn Itọ́kasí

àtúnṣe


Àdàkọ:Nigeria-film-stub