Abọ́lájí Ọmọ́táyọ̀
Abọ́lájí Ọmọ́táyọ̀ Olúwaṣeun tí a bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹfà ọdún 1988 jẹ́ asáré orí ọ̀dàn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ti jáwé olúborí gba àwọn amì-ẹ̀yẹ iríṣríṣi níbi ìdíje eré sísá orí ọ̀dàn fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .[1] Ó ti gba amì-ẹ̀yẹ Wúrà fún ìdíje 4 x 100 nínú ìdíje 2015 African Junior Athletics Championships .
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeÓ ti kópa nínú ìdíje ti àwọn ọ̀jẹ̀ wẹ́wẹ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ọjọ́ orí wọn kò ju ọdún méjìdínlógún lọ tí ó 2014 wáyé ní ọdún (U18), tí ó sì gba ipò kẹta gba àmì-ẹ̀yẹ ''Bàbà'' nínú ìdíje 100 (meters), ní dédé àsìkò 12.57, tí Aniekeme Alphonsus àti Favor Ekezie sì ṣíwájú rẹ̀.[2] Ó tún kópa nínú ìdíje 2014 World Junior Championships in Athletics[3] 2015 Commonwealth Youth Games , tí ó sì gba amì-ẹ̀yẹ Bàbà bákan náà nínú eré 4×100 (metres relay).[4]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Olus, Yemi (2015-04-17). "AFN picks 27 athletes for African Youth Championships". MAKING OF CHAMPIONS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-22.
- ↑ admin. "Dr. D. K. Olukoya National U-18 Champs, Ijebu Ode (Nigeria) 27-28/02/2014 | Africathle" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-10-27. Retrieved 2020-10-22.
- ↑ "4x100 Metres Relay Result | IAAF World Junior Championships 2014". www.worldathletics.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-22.
- ↑ "Meet Results". liveresults.qldathletics.org.au. Retrieved 2020-10-22.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]