Abayomi Oluyomi je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Naijiria lati ipinle Eko ni Naijiria . O ti gba iwe-ẹkọ Bachelor ati Master's ni Finance, Accounting, ati Banking lati University of Lagos . Ni odun 2023, won yan an gẹ́gẹ́ bi Komisana fun eto ìnáwó ni Ìpínlẹ̀ Eko. O tun ti ṣe awọn ipo iṣelu ati olori miiran, pẹlu sise bi Oludamoran Pàtàkì. [1] [2] [3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe