Abba Gumel
ọmọ ẹgbẹ́ ọ̀mọ̀wé ìmọ̀ sáyẹ́nsí ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Abba Gumel jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tó ń kọ́ ẹ̀kọ́ ìṣirò ní University of Maryland, College Park. Iṣẹ́-ìwádìí rẹ̀ dálé lórí ètò ìṣirò. Gumel fìgbà kan kọ́ ìṣirò ní Arizona State University, kí ó tó di alága The Michael and Eugenia Brin Endowed E-Nnovate, ní University of Maryland, College Park, ní ọdún 2022.[1]
Abba B. Gumel | |
---|---|
Gumel in 2022 | |
Pápá | |
Ibi ẹ̀kọ́ | Brunel University London (PhD) |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí |
|