Abd al-Rab Mansur al-Hadi
Ogagun Agba Abd al-Rahman Mansur al-Hadi (Lárúbáwá: عبدالرحمن منصور الهادي; ojoibi 1945[1]) je oloselu ara Yemen to je Igbakeji Aare ile Yemen lati 3 October 1994.[2][3] Won yansipo bi Adipo Aare ni 4 June 2011 nigba aisimi ara Yemen 2011, leyin ti Aare Ali Abdullah Saleh ti ni ipalara leyin idigbolu ile re pelu bombu. Saleh si ni Aare onibise ile Yemen.[4]
Abd al-Rahman Mansur al-Hadi عبدالرحمن منصور الهادي | |
---|---|
Vice President of Yemen | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 3 October 1994 Acting President Since 4 June 2011 | |
Ààrẹ | Ali Abdullah Saleh |
Alákóso Àgbà | Muhammad Said al-Attar Abdul Aziz Abdul Ghani Faraj Said Bin Ghanem Abdul Karim al-Iryani Abdul Qadir Bajamal Ali Muhammad Mujawar |
Asíwájú | Ali Salim al-Beidh |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1945 Abyan, Aden Protectorate (now Yemen) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | General People's Congress |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Yemen's New Acting President: Abd Rabu Who? Waq Al-Waq, Big Think, June 5 2011
- ↑ Central Intelligence Agency, The CIA World Factbook 2008, Skyhorse Publishing, 2007, p. 688
- ↑ Yemen Archived 2011-06-29 at the Wayback Machine. CIA website
- ↑ Al-Hadi acting President of Yemen Al Jazeera Blogs, June 4 2011