Abdalla Hamdok Al-Kinani (tí àwọn míràn ńpè ní Abdallah,[1] Hamdouk, AlKinani; Lárúbáwá: عبدالله حمدوك الكناني‎; ọjọ́ ìbí rẹ̀ ni ọjọ́ Kínní oṣù Kínní ọdún 1956)[2] jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Sudan tí ó jẹ́ mínísítà àgbà Sudan láti ọdún 2019 di oṣù kẹwàá ọdún 2021, àti láti oṣù kẹsàn-án ọdún 2021 di ọjọ́ kejì oṣù Kínní ọdún 2022.[3] Kí ó tó di pé a yàn án sípò yìí, ó ti di ọ̀pọ̀lọpọ̀ ipò adarí mú.[4] láàrin oṣù kọkànlá ọdún 2011 sí oṣù kẹjọ ọdún 2018, òun ni ó jẹ́ igbá-kejì akọ̀wé United Nations Economic Commission for Africa (UNECA).[4][5] Ó wà lára àwọn àádọ́ta ènìyàn tí Bloomberg sọ pé ó nìyí julọ ní ọdún 2020.[6]

Abdalla Hamdok
عبدالله حمدوك
Hamdok in 2019
15th Prime Minister of Sudan
In office
21 November 2021 – 2 January 2022
ÀàrẹSovereignty Council
AsíwájúHimself
Arọ́pòOsman Hussein (acting)
In office
21 August 2019 – 25 October 2021
ÀàrẹSovereignty Council
AsíwájúMohamed Tahir Ayala
Arọ́pòHimself
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kínní 1956 (1956-01-01) (ọmọ ọdún 68)
Al-Dibaibat, South Kordofan, Sudan
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent
Other political
affiliations
Forces of Freedom and Change (until 2021)
(Àwọn) olólùfẹ́Muna Abdalla
Àwọn ọmọ2
EducationUniversity of Khartoum
University of Manchester

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Abdelaziz, Khalid (2019-06-11). "Sudan opposition says to nominate members for transitional council". Reuters. Retrieved 2024-10-21. 
  2. "Abdalla Hamdok: Who is Sudan’s new prime minister?". Al Jazeera. 2019-08-21. Retrieved 2024-10-21. 
  3. "Sudan coup: Prime Minister Abdalla Hamdok resigns after mass protests". BBC Home. 2022-01-02. Retrieved 2024-10-21. 
  4. 4.0 4.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named UNIDO_CV
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named UNECA_farewell
  6. "Abdalla Hamdok, Sudan's Pioneering Reformer". Bloomberg. 3 December 2020. https://www.bloomberg.com/news/articles/2020-12-03/abdalla-hamdok-ex-un-economist-sudan-s-pioneering-reformer-bloomberg-50-2020?leadSource=uverify%20wall.