Abdel Moneim Madbouly
Abdel Moneim Madbouly (Lárúbáwá: عبد المنعم مدبولي, ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1921 – ọjọ́ kẹsàn-án oṣù keje ọdún 2006) jẹ́ òṣeré àti aláwàdà ọmọ orílẹ̀ ède a Íjíptì.[1][2]
Abdel Moneim Madbouly عبدالمنعم مدبولي | |
---|---|
Abdel Moneim Madbouly in 2006 | |
Ọjọ́ìbí | Cairo, Egypt | Oṣù Kejìlá 28, 1921
Aláìsí | July 9, 2006 Cairo, Egypt | (ọmọ ọdún 84)
Iṣẹ́ | Actor, Playwright |
Ìgbà iṣẹ́ | 1949–2005 |
Nípa ayé rẹ̀
àtúnṣeA bí Madbouly sí Cairo, ó sì bẹ̀rẹ̀ isẹ́ òṣeré nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún méje, ó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣiṣẹ́ òṣeré lẹ́yìn ìgbà tí bàbá rẹ̀ kú tí ìdílé rẹ̀ sì nílò owó. Ó padà darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣeré Fatma Rushdi kí ó tó tún darapọ̀ mọ́ ile eré George Abyad.[3]
Madbouly kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ere Íjíptì àti Arab
Àtòjọ àwọn eré tí ó ti kópa
àtúnṣe- In Al-Hawa Sawa: 1951
- My Mom and Me: 1957
- Me and My Heart: 1957
- Love Festival: 1958
- Between Heaven and Earth: 1959
- Heignonne: 1960
- Take Me With You: 1965
- Love for All: 1965
- Kill Me Please: 1965
- In Summer We Must Love: 1974
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Egypt Today. "Opiate of the Masses". Archived from the original on 2006-06-21. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ The Daily Star. "ABDEL MONEIM MADBOULY, RENOWNED EGYPTIAN COMEDIAN, DIES AT 85". Archived from the original on 2007-03-12. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ III., Lentz, Harris M. (2007). Obituaries In the performing arts, 2006 : film, television, radio, theatre, dance, music, cartoons and pop culture. Jefferson, N.C.: McFarland & Co. pp. 222. ISBN 9780786452118. OCLC 320461299.