Abdelmajid Lamriss tí a bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejì, ọdún 1959 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá tó jẹ́ defender fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Morocco.[1][2]

Abdelmajid Lamriss
Personal information
Ọjọ́ ìbí12 Oṣù Kejì 1959 (1959-02-12) (ọmọ ọdún 65)
Ibi ọjọ́ibíMorocco
Ìga1.70 m (5 ft 7 in)
Playing positionDefender (association football)
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
FAR Rabat
National team
1982-1989Morocco national football team47(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals).

Àṣèyọri

àtúnṣe

Abdelmajid ṣeré fún FAR Rabat. Eléré náà ṣeré fún Cup FIFA Àgbáyé ní ọdún 1986[3][4][5].

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe