Abdoulaye Wade
Abdoulaye Wade (ojoibi May 29, 1926)[2] je Aare ile Senegal iketa lati odun 2000 de 2012. Ohun tun ni Akowe-Agba egbe oloselu Senegalese Democratic Party (PDS) ohun si ni olori re lati igba idasile re ni 1974.[3][4] O je olori alatako latojo pipe, o dije fun ipo Aare ni emerin, bere ni 1978, kio to dipe won diboyan wole ni 2000.[3]
Abdoulaye Wade | |
---|---|
President of Senegal | |
In office 1 April 2000 – 2 April 2012 | |
Alákóso Àgbà | Moustapha Niasse Mame Madior Boye Idrissa Seck Macky Sall Cheikh Hadjibou Soumaré Souleymane Ndéné Ndiaye |
Asíwájú | Abdou Diouf |
Arọ́pò | Macky Sall |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kàrún 1926 Kébémer, Senegal |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Senegalese Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Viviane Wade[1] |
Àwọn ọmọ | Karim Wade Sindjely |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Laura Bush hosts Viviane Wade The White House, 6 December 2004
- ↑ World Leaders 2003: Senegal: Personal Background, Encyclopedia of the Nations.
- ↑ 3.0 3.1 Profiles of People in Power: The World's Government Leaders (2003), page 457.
- ↑ Profile of Wade at PDS web site (Faransé).