Àdàkọ:Use Indian English Àdàkọ:Infobox religious biography

Abdul Ghani Azhari (1922 – 19 January 2023), tí a tún mò sí Abdul Ghani Shah al-Shashi,[1] jé omo ilè India tí o jé oní ìmò ìjìnlè àti akoìtàn tí ó se isá gege bíi òjògbón àgbà ní ilé-èkó gíga University of Kashmir ní èka-isé èdè Lárúbáwá. Ó jé akeko jade ní Darul Uloom Deoband, Mazahir Uloom àti Al-Azhar University. Ó se alagbejade Qadim Tarikh-e-Gujjar, ìwé tí ó se àlàyé kikun l'órí ìtàn àwon Gujjars.

Ibeere igbe aye ati eko

àtúnṣe

A bí Abdul Ghani Azhari ní odún 1922 ní Poonch, Jammu ati Kashmir.[2] Ó ka ìwé ní Darul Uloom Deoband, Mazahir Uloom àti Al-Azhar University. Ó ko ìwé àkojáde dókítórèètì l'órí Al-Muslim tí ó pe àkòrí rè ní Al Imam Al Muslim Wa Manhajuhu Fi Al Hadith Riwayatn wa Dirayatan.[2] . Ó kó èkó pèlú Hussain Ahmed Madani, Ibrahim Balyawi, Izaz Ali Amrohi, Muhammad Tayyib Qasmi, àti Syed Fakhruddin Ahmad, àti wípé òkan l'ára àwon olùkó rè ní Mazahir Uloom ni Muhammad Zakariyya Kandhlawi.[3] Ní Azhar, ó kó èkó pèlú àwon onímò ìjìnlè bíi Abdel-Halim Mahmoud.[3]

Azhari jé omo Kashmir tí ó sì se ayeye jíjé omo Gujjar.[4] Ó se ìdásílè Dar al-‘Ulum Nizamiyya Madinatul Islam ní Badshahibagh (l'èbá Saharanpur), tó se ìpèsè fún àwon omo Gurjar.[5] Ó tún se ìdásílè ilé-èkó àwon adarí èsìn ní Kashmir, bíi Maktabah Anwar al Uloom, ní Kokernag, and Darul Uloom Kawthariya l'èbá Dachigam National Park.[6] Ní odún 2003, ó se ìdásílè Darul Uloom Shah Wali Allah in Donipawa, Brakpora, ní Anantnag.[3] Shaikh Abdullah ránsé pèé l'áti wá s'isé gégé bíi òjògbón tí ó n kó èdè Lárúbáwá ní nínú Hazratbal, Srinagarkí ó tó lo da'ra pò mó ilé èkó gíga ti Kashmir.[7]

Àwon ènìyàn rí Azhari gégé bíi oní'mò ìjìnlè èsìn àgbà ni Kashmir. Ó s'isé gégé bíi òjògbón adarí ní èka-isé èdè Lárúbáwá ní ilé èkó gíga University of Kashmir.[8] Ó fi ìnífésí pàtàkì hàn nínú ìlànà ètò Qadiri order ti Sufism tí ó sì se àtèjáde àwon isé l'órí Naqshbandiyyah.[4] Ó fi ayé sí'lè ní ojó kokàndínlógún, osù kíní, Odún 2023. Saharanpur.[9] Salahuddin Tak, tí ó jé òjògbón adarí tí ó n tu'kò èka-isé èdè Lárúbáwá ní ilé èkó gíga náà se àpèjúwe Azhari gégé bíi olùkó takuntakun, onímò èkó nlá àti onímò kíkún pèlú gíga nínú sáyénsì èsìn".[10]

Isé Ìwé

àtúnṣe

Àwon isé Azhari:[11][12]

  • Gujjar Tareekh te Saqafat, compiled by Javaid Rahi[13]
  • Noor-i-Irfan
  • Ma La Budda Minh, a book that he translated from Persian into Urdu
  • Maktubat-i-Naqshbandiyyah
  • Qadim Tarikh-i-Gujjar, a detailed book on the ancient history of Gujjars in India[11][14]

Wo eléyìí náà

àtúnṣe

Ìtókasí

àtúnṣe

Citations

àtúnṣe
  1. Singh 2012, p. 149.
  2. 2.0 2.1 Ahmad 2022, p. 995.
  3. 3.0 3.1 3.2 Ahmad 2022, p. 996.
  4. 4.0 4.1 Singh 2012, p. 151.
  5. Singh 2012, pp. 149–150.
  6. Ahmad 2022, p. 997.
  7. "ماہرین تعلیم و سیاسی رہنماؤں نے مفتی عبدالغنی الازہری کے انتقال پر تعزیت کا اظہار کیا". ETV Bharat. 19 January 2023. https://www.etvbharat.com/urdu/national/state/srinagar/academics-politicians-condole-demise-of-prominent-scholar-abdul-ghani-al-azhari/na20230119194001699699787. 
  8. "AAC expresses condolences with journalist Abid Bashir, Moulana Azhari". Kashmir Reader. 5 July 2022. https://kashmirreader.com/2022/07/05/aac-expresses-condolences-with-journalist-abid-bashir-moulana-azhari/. 
  9. Ayoob, Haseena (19 January 2022). "Renowned scholar from Jammu Abdul Ghani Azhari passes away". The Chenab Times. https://thechenabtimes.com/2023/01/19/renowned-scholar-from-jammu-abdul-ghani-azhari-passes-away/. 
  10. "Academics, politicians condole demise of prominent scholar Abdul Ghani Al-Azhari". Greater Kashmir. 19 January 2022. https://www.greaterkashmir.com/kashmir/academics-politicians-condole-demise-of-prominent-scholar-abdul-ghani-al-azhari. 
  11. 11.0 11.1 Ahmad 2022, p. 999.
  12. "معروف عالم دین مفتی عبدالغنی الازہری سہارنپور میں انتقال کرگئے". Kashmir Uzma. 20 January 2023. https://kashmiruzma.net/%D9%85%D8%B9%D8%B1%D9%88%D9%81-%D8%B9%D8%A7%D9%84%D9%85-%D8%AF%DB%8C%D9%86-%D9%85%D9%81%D8%AA%DB%8C-%D8%B9%D8%A8%D8%AF%D8%A7%D9%84%D8%BA%D9%86%DB%8C-%D8%A7%D9%84%D8%A7%D8%B2%DB%81%D8%B1%DB%8C/. 
  13. "Mian Altaf releases latest Gojri publications". Scoop News. https://scoopnews.in/det.aspx?q=15026. 
  14. "قديم تاريخ گجر / Qadīm tārīk̲h̲-i Gujar". WorldCat. Archived from the original on 21 January 2023. Retrieved 20 January 2023.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)

Ìwé Ìtàn gbogbogbò

àtúnṣe
  • Ahmad, Naikzada Mehmood (November 2022). "The Untold legacy of Professor Mufti Abdul Ghani Al Azhari". Journal of Emerging Technologies and Innovative Research 9 (11): 995–1000. ISSN 2349-5162. 
  • Singh, David Emmanuel (2012). Islamization in Modern South Asia: Deobandi Reform and the Gujjar Response. De Gruyter. pp. 149–152. 

Kíkà síwájú síi

àtúnṣe

Àdàkọ:Authority control