Abdul Hai Arifi
Àdàkọ:Use Pakistani English Àdàkọ:Infobox office holder Abdul Hai Arifi (1898–27 March 1986) jé òmòwé mùsùlùmí omo ilè Pakistani àti olùtóni Sufi ti ìlànà Chishti order. Ó jé omo èyìn Ashraf Ali Thanwi. Ó se ìtèjáde àwon ìwé bíi Uswah Rasool-e-Akram àti Ikú àti ogún. Ó s'isé gégé bíi ààre ti Darul Uloom Karachi .fún bíi odún méwà.
Arifi jé akékò jáde ti ilé-èkó Muhammadan Anglo-Oriental College àti ti University of Lucknow. Ó se isé agbejórò l'àárín odún 1926 àti 1935, àti èkó ìtójú àìsàn nípasè ohun kékèèké homeopathy láti odún 1936 títí ti o fi fi aye sí'lè ni ojó ketàdínlógbòn, osù keta odún 1986. Àwon akékò rè kan ni Sufism ni Muhammad Taqi Usmani àti Muhammad Rafi Usmani.
Ìgbésí ayé
àtúnṣeA bí Abdul Hai Arifi ni odún 1898 ni United Provinces of British India.[1] Ó jade ni ilé-ìwé girama Muhammadan Anglo-Oriental College ní odún 1923 ti ó sì gba oyè LLB degree láti ilé-èkó giga University of Lucknow. Ó se isé agbejórò l'àárín odún 1926 àti 1935.[1] Ó fi isé náà sí'lè ti ó sì lo ko isé Homeopathy ni odún 1936. Ó se isé dókítà homeopathy títí ó fi mi èémí ìgbèyìn.[2] Ó sì ti ni àjosepò pèlú Ashraf Ali Thanwi láti odún 1923, tí ó sì di "murid" re ní odún 1927. Thanwi fun ní àkóso ní ìlànà ètò ti Chishti order ni odún 1935.[2]
Arifi jé omo egbé ìsàkóso ti Darul Uloom Karachi tí ó sì di adarí dípò Muhammad Shafi Deobandi gégé bíi ààre Darul Uloom Karachi ti ó sì s'isé sin ilé-èkó ìmò èsìn fun bíi odún méwàá títí ó fí fi ayé sí'lè.[3] ó fi ayé sí'lè ni ojó ketàdínlógbòn osù keta, odún 1986.[4] Muhammad Taqi Usmani ni ó darí àdúrà ìsìnkú re tí Muhammad Zia-ul-Haq àti Jahan Dad Khan [5] sí wà ní'bè. Won sin-ín sí inú ité-òkú ti Darul Uloom Karachi.[6] Ara àwon omo l'éyìn rè ni Muhammad Taqi Usmani[7] àti Muhammad Rafi Usmani.[8]
Isé ìwé
àtúnṣeArifi se àgbéjáde àwon ìwé bíi:[9]
- Uswah Rasool-e-Akram
- Death and Inheritance
- Ashraf Ali Thanvi, life & works
- The Islamic way in death: an authentic and comprehensive handbook of rules, and conduct in the event of death among Muslim
- Maʼās̲ir-i Ḥakīmulummat : irshādāt va ifādāt
- K̲h̲avātīn ke sharʻī aḥkām
- Fihrist-i taʼlīfāt-i Ḥakīmulummat
- Bahādur Yār Jang Akādmī kā taʻāruf
Àsesílè
àtúnṣeMuhammad Rafi Usmani wrote Mere murshid Ḥaẓrat-i ʻĀrifī[8] and Sayyid Riyazuddin wrote Ārif Billāh Ḥaz̤rat Ḍākṭar Muḥammad ʻAbdulhaʼī: savāniḥ ḥayāt va taʻlīmāt.[10]
Wo eyí náà
àtúnṣeÀtókasí
àtúnṣeCitations
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Parvez 2008, p. 161.
- ↑ 2.0 2.1 Parvez 2008, p. 162.
- ↑ Usmani 2014, p. 71.
- ↑ Sana'ullah Saad Shuja'abadi 2015, p. 221.
- ↑ Sana'ullah Saad Shuja'abadi 2015, p. 228.
- ↑ Parvez 2008, p. 163.
- ↑ "Profile of Muhammad Taqi Usmani on Muslim500". muslim500.com. Retrieved 25 December 2020.
- ↑ 8.0 8.1 Usmani, Muhammad Rafi. Mere Murshid Hazrat-e-Aarifi. OCLC 1045663631. https://www.worldcat.org/oclc/1045663631. Retrieved 25 December 2020.
- ↑ "Abdul Hai Arifi on WorldCat". worldcat.org. WorldCat. Retrieved 25 December 2020.
- ↑ Sayyid Riyāz̤uddīn. ʻĀrif Billāh Ḥaz̤rat Ḍākṭar Muḥammad ʻAbdulhaʼī: savāniḥ ḥayāt va taʻlīmāt. OCLC 36204814. https://www.worldcat.org/oclc/36204814. Retrieved 25 December 2020.
Ìwé ìtàn
àtúnṣe- Sana'ullah Saad Shuja'abadi, Abu Muhammad (2015). "Hadhrat Mawlāna Dr Abdul Hai Arifi" (in Urdu). Ulama-e-Deoband Ke Aakhri Lamhaat. Saharanpur: Maktaba Rasheediya. pp. 221–228.
- Àdàkọ:Cite thesis
- Usmani, Muhammad Rafi (2014). Mere Murshid Hazrat Arifi. Karachi: Idaratul Ma'arif.