Umaru Farouk Abdul Mutallab

(Àtúnjúwe láti Abdulfarouk Umar Muttalab)

Umaru Farouk Abdul Mutallab je omo orile-ede Naijiria to je fifesunkan pe o tiraka lati yin bombu abefanka ninu ifoloke 253 baalu ti Northwest Airlines ni Ojo Keresimesi December 25, 2009.

Umar Farouk Abdul Mutallab
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Kejìlá 1986 (1986-12-22) (ọmọ ọdún 38)
Lagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Degree in mechanical engineering
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity College London
Gbajúmọ̀ fúnAttempted attack on Northwest Airlines Flight 253, December 25, 2009
Parent(s)Umaru Mutallab (father)