Abdulla Baba Fatadi
Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà
Abdulla Baba Fatadi tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejì Oṣù Kọkànlá ọdún 1985 (2nd November 1985) jẹ ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà agbábọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá fún orílẹ̀ èdè Bahraini.[3] Ó jẹ́ olùdarí fún ẹgbẹ́ Al Jahra . Orukọ àbísọ rẹ̀ ni Babatunde Fatai. Ó gbá Bọ́ọ̀lù Àfẹsẹ̀gbá fún orílẹ̀ èdè Naijirialábala àwọn ọ̀jẹ̀wẹ́wẹ́ tí ọjọ́ orí wọ́n kò ju mẹ́tàdínlógún (17) lọ kí ó tó sọ ara rẹ̀ di ará orilẹ-èdè Bahrain lọ́dún 2004.
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Babatunde Fatai-Baba Fatai | ||
Ọjọ́ ìbí | 2 Oṣù Kọkànlá 1985 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Lagos, Nigeria | ||
Ìga | 1.76 m (5 ft 9 in) | ||
Playing position | Midfielder[1] | ||
Youth career | |||
2000–2002 | Osaka Fc Lagos | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2002–2004 | Al Najma Club | 31 | (13) |
2004–2006 | Al Ahli Club | 28 | (12) |
2006–2008 | Muharraq Club | 30 | (14) |
2008–2009 | Al-Kharitiyath S.C. | 23 | (2) |
2009–2010 | Neuchâtel Xamax | 17 | (1) |
2010–2011 | w:Ittihad Kalba | 10 | (0) |
2011 | Al-Qadisiyah FC[2] | 10 | (1) |
2011–2012 | Al Jahra | 19 | (3) |
2012–2013 | Al-Shoalah | 11 | (0) |
– | Al-Hidd | ||
National team‡ | |||
2007–2012 | Bahrain | 46 | (8) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 1 August 2011. † Appearances (Goals). |
Awọn ifojusi fun ẹgbẹ orilẹ-ede giga
àtúnṣe# | Ọjọ | Ibugbe | Alatako | O wole | Esi | Idije |
---|---|---|---|---|---|---|
21 Oṣu Kẹwa 2007 | Manama , Bahrain | Malaysia | 4-1 | Won | FIFA Iwọn Agbaye FIFA 2010 | |
16 January 2007 | Manama , Bahrain | Kuwait | 1-0 | Won | Ore | |
26 January 2008 | Manama , Bahrain | Yemen | 2-1 | Won | Ore | |
10 Kẹsán 2008 | Doha , Qatar | Qatar | 1-1 | Fọ | FIFA Iwọn Agbaye FIFA 2010 | |
21 January 2009 | Hong Kong , Hong Kong | ilu họngi kọngi | 3-1 | Won | 2011 AFC Asian Cup qualification | |
23 Oṣù 2009 | Manama , Bahrain | Zimbabwe | 5-2 | Won | Ore | |
18 Kọkànlá Oṣù 2009 | Manama , Bahrain | Yemen | 4-0 | Won | 2011 AFC Asian Cup qualification | |
29 Kọkànlá Oṣù 2011 | Aden , Yemen | Apapọ Arab Emirates | 1-3 | Isonu | 2010 Gulf Cup of Nations |
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ "Abdulla Baba Fatadi Stats, News, Bio". ESPN. November 22, 2022. Retrieved November 22, 2022.
- ↑ "Abdulla Baba Fatadi". worldfootball.net. November 2, 1985. Retrieved November 22, 2022.
- ↑ Strack-Zimmermann, Benjamin (November 2, 1985). "Abdulla Baba Fatadi (Player)". National Football Teams. Retrieved November 22, 2022.