Abdullah Gül, GCB, GColIH, Ph.D. (ojoibi October 29, 1950) ni Aare ikokanla lowolowo orile-ede Turki lati 28 August 2007. Teletele o ti je Alakoso Agba ile Turki lati 2002 de 2003, o si tun je Alakoso Oro Okere ile Turki lati 2003 de 2007.

Abdullah Gül
11th President of Turkey
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
28 August 2007
Alákóso ÀgbàRecep Tayyip Erdoğan
AsíwájúAhmet Necdet Sezer
Prime Minister of Turkey
In office
18 November 2002 – 14 March 2003
ÀàrẹAhmet Necdet Sezer
AsíwájúBülent Ecevit
Arọ́pòRecep Tayyip Erdoğan
Minister of Foreign Affairs
In office
14 March 2003 – 28 August 2007
Alákóso ÀgbàRecep Tayyip Erdoğan
AsíwájúYaşar Yakış
Arọ́pòAli Babacan
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kẹ̀wá 1950 (1950-10-29) (ọmọ ọdún 74)
Kayseri, Turkey
(Àwọn) olólùfẹ́Hayrünnisa Gül
Alma materIstanbul University
University of Exeter
SignatureAbdullah Gül
WebsiteTccb.gov.tr