Abdulmalik Jauro Musa je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Ó sìn gẹ́gẹ́ bí igbákejì Ọlọpa ile ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Adamawa tó ń ṣojú ẹkùn ìpínlẹ̀ Ganye . O ku ni inú Oṣu Karùn-ún ọdun 2024. [1] [2] [3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe