Abdulrahman Bello Dambazau

Olóṣèlú

Abdulrahman Bello Dambazau (ojoibi March 14, 1954) jé ológun pèlú okùn ògágun Onígbákejì tó tí feyintì láti Agbogun ará Naìjíríà àti lówólówó Alákòso ètò Abélé Naìjíríà. Dambazau síse bí ògá Omosé Agbógun Naìjíríà (COAS) láàrín 2008 àtí 2010, nígbà tó gbéyìn ògágun ònígbákejì Luka Yusuf.

Abdulrahman Bello Dambazau
Ogagun Onigbakeji

Abdulrahman Bello Dambazau Ìkọ kedere
Federal Minister of the Interior
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
November 2015
AsíwájúPatrick Abba Moro
Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Agbógun Nàìjíríà
In office
2008–2010
AsíwájúLuka Yusuf
Arọ́pòAzubuike Ihejirika
General Officer Commanding 2 Division, Ibadan
In office
2007–2008
AsíwájúMaj-Gen M.S. Saleh
Arọ́pòMaj-Gen Lawrence Ngubane
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1954-03-14)14 Oṣù Kẹta 1954
Zaria, Kaduna State, Nigeria
Alma materBarewa College
Nigerian Defence Academy
Kent State University
University of Keele
Military service
Allegiance Nigeria
Branch/serviceNigerian Army
RankLieutenant General

Àdàkọ:Èkúnréré

ìtókasí

àtúnṣe