Abel Oluwafemi Dosumu
Abel Oluwafemi Dosumu tí orúkọ gbajúgbajà rẹ̀ ń jẹ́ Mega99 ni wọ́n bí sí Oshòdi, ìlú ńlá ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ìpín ìsàkóso ti Nàìjíríà . Ó gba oyè Ìmọ̀ Sáyẹ́ńsì (BSc) nínú Ìmọ̀ Ìṣirò-owó láti Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Ọlábísí Onàbánjọ.[1][2][3]
Mega 99 | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Oshodi, Lagos State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1994–present |
Ní ọdún 1994, ó dá ẹgbẹ́ olórin kan sílè tí wọ́n pè ní Abel Dosunmu àti Mega 9'9 Band.[4][5] Àwo orin àkọ́kọ́ rẹ̀ tó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Ìyá mi jẹ́ gbígbé jáde ní ọdún 1998 àti àwo orin mìíràn tí wọ́n pe àkọ́lé rẹ̀ ní Àdúrà jẹ́ gbígbé jádé lọ́dun 2000 ṣùgbọ́n ó di gbajúmọ̀ nípa àwo orin rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Owó, tí ó jáde ní ọdún 2004. Lẹ́yìn náà, ó tún gbé “Ọ̀nà Àrà” jáde ní ọdún 2006, tí “Má Sukún Mọ́” sì tẹ̀lé e ní ọdún 2008 àti Ìdúpẹ́ ní ọdún 2010. Àwo-orin mìíràn tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Ìṣẹ́gun Ní Ìkẹ̀yìn jẹ́ gbígbé jáde ní ọdún 2012, Máṣe bẹ̀rù” ní ọdún 2013 àti "Ẹ máa jó Ẹ máa yọ̀" ní ọdún 2014.[6][7] Mega 99 tún ti kọ orin papọ̀ pẹ̀lú àwọn akọrin ìyìnrere mìíràn ní Nàìjíríà bíi Bọ́lá Àrẹ. [8]
Àtòpọ̀ Àwọn Orin
àtúnṣe- Ìyá mi (1998)
- Àdúrà (2000)
- Owó (2003)
- Ọ̀nà Àrà (2006)
- Máṣe sọkún (2008)
- Ìdúpẹ́ (2010)
- Máṣe bẹ̀rù (2013)
- Ẹ máa jó Ẹ máa yọ̀(2014)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Mega 99 shows class at Opelope Anointing bash". The Punch. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 15 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Our Reporter. "Atorise, Mega 99 thrill at Apata's album launch". The Nation. Retrieved 15 March 2015.
- ↑ "Lavish praises to God for 2012". Daily Independent, Nigerian Newspaper. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 15 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Juju thrives on quality beats – Mega 99". The Punch. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 15 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Latestnigeriannews. "Juju thrives on quality beats ' Mega 99". Latest Nigerian News. Retrieved 15 March 2015.
- ↑ "In Fear Not, Mega 99 sings a new song". The Punch. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 15 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Licking honey, Mega 99 sings victory song". The Punch. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 15 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Empty citation (help)