Abel Pacheco de la Espriella (ojoibi 22 Osu Kejila, 1933, ni San José) lo je Aare ile Kosta Rika lati 2002 di 2006, o je omo egbe oloselu (Partido Unidad Social Cristiana – PUSC).[1]

Abel Pacheco de la Espriella
Abel Pacheco
Aare ile Kosta Rika
In office
May 8, 2002 – May 8, 2006
AsíwájúMiguel Ángel Rodríguez Echeverría
Arọ́pòÓscar Arias Sánchez
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Kejìlá 1933 (1933-12-22) (ọmọ ọdún 91)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPUSC
(Àwọn) olólùfẹ́Leila Rodríguez Stahl
ProfessionPsychiatrist


  1. Pacheco assumes presidency. The Salt Lake Tribune. May 9, 2002, PageA2. [1]