Olasupo Abideen Opeyemi (tí àbí ní October 17, 1993) ní ìlú Ifọ́n ní ìpínlẹ̀ Osun, ó jẹ́ oníṣòwò orílè èdè Nàìjíríà, Ó jẹ́ olùdásílè ilé-iṣẹ́ OPAB Gas àti Brain Buiders Youth Development Initiative (BBYDI). Ó sì jẹ́ ìkan lára alágbàwí SDGs.[1][2]

Abideen Olasupo
Ọjọ́ìbíOctober 17, 1993
Ifon, Osun State
Iṣẹ́

UN pe Olasupo Abideen láti sọ̀rọ̀ ní 2023 Economic Economic and Social Council ( ECOSOC ) Youth Forum tí ó sọ̀rọ̀ lórí kókó ọ̀rọ̀ yìí "Strengthening the Trust of Youth in Multilateralism: Exploring Intergenerational and Peer-to-Peer Dialogue.[3] Intergenerational Wọ́n tún dárúkọ rẹ̀ lára àwọn ọ̀dọ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ tí ọ́ máa sọ̀rọ̀ ní UNGASS lórí àwọn ọ̀rọ̀ àti ojútùú fún dídènà àti gbígbógun ti ìwà ìbàjẹ́ àti fífi ìfọwọ́sowọ́pọ̀ kárí ayé.[4]

Ita ìjápọ

àtúnṣe

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. Owoyele, Tola (2021-12-14). "CLOSE-UP: Olasupo Abideen, Nigerian Who Returned $2,397 Excess Payment Amid Curses and Jeers". Foundation For Investigative Journalism (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-05. 
  2. "OLASUPO Abideen Opeyemi | Sahara Reporters". saharareporters.com. Retrieved 2023-07-05. 
  3. Ileyemi, Mariam (2023-04-25). "Young Nigerian entrepreneur to speak at UN event". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-10. 
  4. Rasak, Adekunle (2021-05-24). "27-year-old Abideen to represent Nigeria at UN Corruption Summit". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-07-10.