Abiodun Abodunde
[Abíọ́dùn Abọ́dúndé]]
Olùkó lítírésò ni Ọ̀jọ̀gbọ́n Abíọ́dùn Abọ́dúndé ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ èdè àti Lítíréṣọ̀ Áfíríkà ní Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, Ilé ifẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ ni Ọ̀jọ̀gbọ́n yìí ṣe lórí Àlọ́, kódà, púpọ̀ nínú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ dá lé Àlọ́ onítàn. Ó síṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ yìí kí ó tó fẹ̀yìntì. Léyìn rẹ̀ ni ó ṣe aláìsí lẹ́yìn àìsàn ráńpẹ́.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |