Abiodun Obafemi
Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà
Abiodun Obafemi (ojoibi 25 December 1973 ni Lagos) je agba boolu-elese ara Naijiria. O je agbeyin to gba opo boolu re ni Jermani, o si je omo-egbe agba boolu to gba Eso Wura fun Naijiria ni Olimpiki 1996.
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Abiodun Olugbemiga Obafemi | ||
Ọjọ́ ìbí | 25 Oṣù Kejìlá 1973 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Lagos, Nigeria | ||
Ìga | 1.84 m (6 ft 1⁄2 in)[1] | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1992–1993 | Stationery Stores | ||
1993–1994 | Fortuna Köln | ||
1994–1997 | Fortuna Düsseldorf | 1 | (0) |
1995–1996 | → Toulouse (loan) | 25 | (0) |
1997–2000 | SSV Reutlingen | 41 | (0) |
2000–2001 | FC Augsburg | 9 | (0) |
National team | |||
1997 | Nigeria | 2 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki | |||
Adíje fún Nàìjíríà | |||
---|---|---|---|
Men's Football | |||
Wúrà | 1996 Atlanta | Team Competition |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Obafemi, Abiodun" (in German). kicker.de. Retrieved 17 July 2013.