Abiola Babes jẹ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá jẹun nígbà kan rí, ní ìlú Abẹ́òkúta lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Àgbà òṣèlú, olóògbé Bashorun Moshood K Abiola ní ó ni ín. Wọ́n gba ìgbéga sí ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù Àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lọ́dún 1984.

Lodun 2000, àtúnṣe dé bá ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá náà, ṣùgbọ́n wọ́n gbé ààlè lé wọn lọ́dún 2001 nítorí ìṣòro àìlówó. [1][2] Their last game was in the 2001 Challenge Cup against NIPOST FC.[3]

Àwọn Àṣeyọrí

àtúnṣe
  • Olùbórí nínú ìdíje ipele kejì lọ́dún 1983(Nigeria 2nd Division Champion

1983)

Akitiyan wọn nínú ìdíje CAF

àtúnṣe
1986: Wọn já kulẹ̀ lábala àkọ́kọ́
1987: Wọn pegedé sí aba tó ká gún sí àṣekág á (Semifinals)

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe