Èdè Abkhaz

(Àtúnjúwe láti Abkhaz language)


Èdè kan ni eléyìí lára àwọn èdè tí a ń pè ní Abkhazo-Adyghian tí àwọn wọ̀nyí tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ fún àkójọpọ̀ èdè tí a ń pè ní caucasian (Kọ̀kọ́síànù). Àwọn tí ó ń sọ Abkhaz tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgọ́rùn-ún ènìyàn ní ìpínlẹ̀ tí a ń pè ní Abkhaz ní Georgia. Ó wà lára àwọn èdè ti ìjọba ń lò níbẹ̀. Wọ́n tún ń sọ èdè yìí ní apá kan ilẹ̀ Tọ́kì (Turkey).

Abkhaz
Аҧсуа бызшәа; аҧсшәа
Sísọ níTurkey, Russia, Georgia, Jordan, Syria, Iraq
Abkhazia (Recognized as independent by Russia, Nauru, Nicaragua, and Venezuela)
AgbègbèCaucasia
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀125 000
Èdè ìbátan
Sístẹ́mù ìkọAbkhaz alphabet
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Àkóso lọ́wọ́Kòsí àkóso oníbiṣẹ́
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1ab
ISO 639-2abk
ISO 639-3abk

àkọtọ́ Cyrillic (Sìríhìkì) ni wọ́n fi ń kọ èdè yìí sílẹ̀.