Olóyè Abraham Aderibigbe Adesanya /θj/ (24 July 1922 – 27 April 2008) fìgbà kan jé olóṣèlú, agbẹjọ́rò, ajìjàgbara ọmọ orílè-èdè Naijiria.[1]

Chief
Abraham Adesanya
Ọjọ́ìbíAbraham Aderibigbe Adesanya
24 July 1922
Ijebu Igbo, Southern Region, British Nigeria (now in Ogun State, Nigeria)
Aláìsí27 April 2008(2008-04-27) (ọmọ ọdún 85)
Ọmọ orílẹ̀-èdè
Iléẹ̀kọ́ gígaHolborn College of Law
Iṣẹ́
  • Politician
  • lawyer
  • activist
Political partyAction Group
Olólùfẹ́Rosannah Arinola Adesanya
Àwọn ọmọ
  • Adebayo Adesanya
  • Oluwasegunfunmi Adesanya
  • Modupeola Adesanya Adelaja
  • Olufemi Adesanya
Parents
  • Ezekiel Adesanya (father)
  • Elizabeth Odiya Adesanya (mother)

Òun ni ọmọ gbagbúgbaja Oloye Ezekiel Adesanya (tí àwọn ènìyàn tún ń pè ní Baba Obu’keagbo), tó wà láyé ní sẹ́ńtúrì kọkàndínlógún, tí ìyà rẹ̀ sì ń jẹ́ diya Adesanya. Ó fẹ́ arábìnrin Rosannah Arinola Adesanya, née Onafalujo, èyí tó kú lẹ́yìn ọdún kejì tí ọkọ rẹ̀ kù. Wọ́n jìjọ bí ọmọ mẹ́rin, àwọn ni: Adebayo Adesanya, Oluwasegunfunmi Adesanya, Modupeola Adesanya Adelaja àti Olufemi Adesanya. Wọ́n ní àwọn ọmọ-ọmọ mẹ́wàá.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Obasanjo: How Abraham Adesanya rejected me thrice". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-02. Retrieved 2022-03-09.