Abubakar S. Sambo

ọmọ ẹgbẹ́ ọ̀mọ̀wé ìmọ̀ sáyẹ́nsí ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà

Abubakar Sani Sambo OON</link> (Tí a bí 31 july 1955) jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ Mechanical ọmọ orílẹ-èdè Nàìjíríà, Alákóso Àgbà tẹ́lẹ̀ ti Energy Commission of Nigeria (ECN), Alága ti Ìgbìmọ̀ Ọmọ ẹgbẹ́ Nàìjíríà ti World Energy Council (WEC), Ẹkun Áfíríkà àti vice- Chancellor ti Abubakar Tafawa Balewa University, Nigeria.

Ìgbésí ayé ìbẹrẹ àti ẹ̀kọ́ àtúnṣe

Wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlelọ́gbọ̀n oṣù Kèje ọdún 1955 ní ìlú Zariaìpìnlẹ̀ Kaduna ní orílẹ-èdè Nàìjíríà . Ó gba òye Bachelor of Science (B.sc) ni mechanical Engineering láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Ahmadu Bello University, Zaria ní ọdún 1979 pẹ̀lú first class. Ní ọdún 1983, ó gba òye dókítà kan, Ph.D. ní mechanical Engineering láti University of Sussex, United Kingdom . [1] Lẹyìn tí ó ti gbà Ph.D, ó padà sí Nàìjíríà láti darapọ̀ mọ́ iṣẹ́ ti Bayero University, Kano níbi tí o ti dìde sí ipò olúkọni àgbà ní ọdún 1989 tí ó sì yan olùkọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní ẹ̀kọ́ agbára ní University kannáà. Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí igbákejì Yunifásítì Abubakar Tafawa Balewa ní ọdún 1995 ó sì ṣiṣẹ́ ní ipò yìí fún ìgbà méjì (1995-2004). Òun ni incumbent director-general and chief executive of Nigeria (ECN) ati vice Chairman of the world Energy Council (WEC), Agbègbè Áfíríkà, láti Oṣù kọkànlá ọdún 2007. [2]

Àwọn ẹbùn àtúnṣe

  • Officer of the order of the Niger, OON

Àwọn ẹlẹ́gbẹ́ àti ẹgbẹ́ àtúnṣe

  • Fellow of the Nigerian Academy of Engineering
  • Fellow of the Nigerian Society of Engineers
  • Member of the council for the Regulation of Engineering in Nigeria (COREN)
  • International Solar Energy Society (ISES) (1986)
  • International Energy Foundation (IEF) (1990)
  • Member of the world Renewable Energy Network (WREN) (1992).
  • Member of the solar Energy society of Nigeria
  • Member of the Nigerian Academy of Science

Wo eléyi náà àtúnṣe

  • Àkójọ ti àwọn Enginners ní Nigeria
  • Àkójọ ti àwọn igbákejì Chancellor ní Nigeria

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Empty citation (help) 
  2. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2014-12-10. Retrieved 2024-02-12.