Abunuabunu
Oúnjẹ ilẹ̀ Ghana
Abunuabunu jẹ́ ọbẹ̀ láti ìgbèríko Brong Ahafo Region ti Ghana.[1][2] a ṣe é láti ara ewé kókò cocoyam (ní ìbílẹ̀, tí wọ́n ń pè ní kontomire) papọ̀ pẹ̀lú àwọn èròjà mìíràn(tomatoes, ìgbín, ẹja yíyan, àlùbọ́sà, ata aláwọ̀ ewé, tòlótòló (Asante - twi kwahu nsusua) àti iyọ̀).[3][4][5]
Place of origin | Ghana |
---|---|
Created by | Akan people |
Serving temperature | Hot |
Main ingredients | cocoyam leaves (kontomire), tomatoes, snails, smoked fish, onions, pepper, kwansesaawa and salt |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
It is commonly found and prepared among people in Kumasi,[6] sometimes with fufu or banku.[7]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Going green with Abunuabunu". www.pulse.com.gh (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-08-16. Retrieved 2019-04-30.
- ↑ "Pulse Tv- Efie Aduane Episode 7- How To Prepare Abunuabunu | WatsupAfrica - Africa's Latest News & Entertainment Platform" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-30.
- ↑ "How to prepare 'Ebun ebunu' (Kontomire soup)". www.pulse.com.gh (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-02-01. Retrieved 2019-04-30.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "How To Prepare The Green Soup called Ebunubunu.". Naa Oyoo Quartey (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-30.
- ↑ "Nanaaba's Kitchen-how to make ebunuebunu soup (green soup)". AfroTide (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-07. Retrieved 2019-04-30.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ davidmawuligh (2016-07-19). "5 delicious meals you will surely get to enjoy in Kumasi". Ghanafuo.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-30.
- ↑ "JOSELYN DUMAS SPOTTED ENJOYING FUFU AND ABUNUABUNU". Nkonkonsa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-08-17. Retrieved 2019-04-30.