Ẹ̀bùn Ọ́skà
(Àtúnjúwe láti Academy Award)
Àwọn Ẹ̀bùn Akádẹ́mì tàbí Ẹ̀bùn Ọ́skà jẹ́ ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù tí American Academy of Motion Picture Arts and Sciences ma ń fún olùdarí eré, òṣèrè àtí olùkọ̀tàn fún iṣẹ́ takuntakun ní ilé iṣẹ́ fíìmù.[1] Ayẹyẹ ẹ̀bùn yìí jẹ́ ìkan lára àwọ́n ayẹyẹ èbùn tó lókìkí jùlọ ní gbogbo àgbáyé. Osì tún jẹ́ Ayẹyẹ ẹ̀bùn tó pẹ́ júlọ tí ó si ma ń dàgbeléwò lórí ẹ̀rọ amóùnmáwòran ní orílẹ̀ èdè tó ju igba lọ. Aẁọn ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù bi tiẹ̀ ni Grammy Awards (fún orin), Emmy Awards (fun amóùnmáwòran), àti Tony Awards (fún tíát̀à)
Ẹ̀bùn Ọ́skà | |
---|---|
Ère ẹ̀bùn ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fíìmù Amẹ́ríkà | |
Bíbún fún | fún iṣẹ́ takuntakun ní ilé iṣẹ́ fíìmù Améríkà |
Látọwọ́ | Academy of Motion Picture Arts and Sciences |
Orílẹ̀-èdè | Amẹ́ríkà |
Bíbún láàkọ́kọ́ | May 16, 1929 |
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ | Oscars.org |
Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "About the Academy Awards". Academy of Motion Picture Arts and Sciences. Archived from the original on April 7, 2007. Retrieved April 13, 2007.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |