Òjò oníkíkan
(Àtúnjúwe láti Acid rain)
Òjò oníkíkan (Acid rain) je iru ojo tabi iru ìrọ̀sílẹ̀ miran to unsaba je kikan, eyun pe o ni ipele giga awon ioni haidrojin (pH kekere). O le ni ewu si awon ogbin, awon eranko inu omi, ati si ohun miran oriile to ba fon si won. Idie ti ojo kikan se unsele i nitori itujade sulfur oloksijinmeji ati nitrojin oloksijin ti won undarapo mo awon owon omi ninu afefeayika lati da onikikan.