Adágún Dem jẹ́ adágún omi kan ní àríwá Burkina Faso tí ó wà àríwá Kaya, gúúsù Sahel Reserve àti ní ilà-oòrùn Lake Bam. Ó sàn sínú White Volta.[1] Ó gùn tó kìlómítà márùn-ún, ó sì fẹ̀ tó kìlómítà méjì.[1] Adágún náà wà ní ara àwọn ìlẹ̀ Ramsar láti ọdún 2009.[2]

Adágún Dem
Location Burkina Faso
Coordinates 13°11′43″N 1°09′02″W / 13.19528°N 1.15056°W / 13.19528; -1.15056Coordinates: 13°11′43″N 1°09′02″W / 13.19528°N 1.15056°W / 13.19528; -1.15056
Primary outflows White Volta
Basin countries Burkina Faso
Max. length 5 km (3.1 mi)
Max. width 2 km (1.2 mi)
Surface elevation 304 m (997 ft)

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Mepham, Robert; R. H. Hughes; J. S. Hughes (1992). A directory of African wetlands. IUCN. pp. 316. ISBN 2-88032-949-3. https://books.google.com/books?id=VLjafeXa3gMC&pg=PA316. 
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named RSIS