Adágún Higa ni adágún kan ní ìlà-oòrùn Burkina Faso, ní ẹgbẹ́ àlà Niger. Ó sàn wọnú Babangou, tí ó sàn wọnú odò Niger.[1] Ó fẹ̀ tó 228 ha.[1] Ó sì ga tó 271 m (889 feet).[2] Ní ọdún 2009, wọ́n fi kún ara àwọn ilẹ̀ Ramsite.[3]

Adágún Higa
Location Burkina Faso
Coordinates 13°36′49″N 0°43′18″E / 13.613622°N 0.721664°E / 13.613622; 0.721664Coordinates: 13°36′49″N 0°43′18″E / 13.613622°N 0.721664°E / 13.613622; 0.721664
Primary outflows Babangou
Basin countries Burkina Faso
Surface area 228 ha (560 acres)
Surface elevation 271 m (889 ft)

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Mepham, Robert; R. H. Hughes; J. S. Hughes (1992). A directory of African wetlands. IUCN. pp. 316. ISBN 2-88032-949-3. https://books.google.com/books?id=VLjafeXa3gMC&pg=PA316. 
  2. "Burkina Faso Lakes". Index Mundi. 2006. Retrieved 13 March 2010. 
  3. Kibata, Cynthia (1 October 2009). "Twelve new Ramsar sites in Burkina Faso". Ramsar Convention. Retrieved 13 March 2010.