Adán Jodorowsky or Adanowsky (tí wọ́n bí ní 29 October 1979) jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Mexico, tó tan mọ́ ìlú Fránsì. Ó sì tún jẹ́ òṣèrékùnrin àti adarí-eré.
Adán Jodorowsky
Jodorowsky in 2017
Background information
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi
Adanowsky
Ọjọ́ìbí
29 Oṣù Kẹ̀wá 1979 (1979-10-29) (ọmọ ọdún 45) Paris, France