Adebayo Salami

Olóṣèlú Naijiria
(Àtúnjúwe láti Adébáyọ̀ Sàlámì)

Adébáyọ̀ Sàlámì tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ọ̀gá Bello (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Kẹ̀sán-án oṣù karùn-ún ọdún 1953) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1][2]

Adebayo Salami
Adébáyọ̀ Sàlámì
Ọjọ́ìbí9, May 1953
Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànOga Bello
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actor, filmmaker and film director
Ìgbà iṣẹ́1964-present
Àwọn olùbátanFemi Adebayo (omo rè okunrin)
Kemi Adebayo (omo rè obinrin)
Tope Adebayo(omo rè okunrin)




Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe