Ada Udechukwu
Ada Udechukwu (bii ni odun 1960) je osere ati akewi ni orile ede Naijiria.
Ada Udechukwu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1960 Enugu, Naijiria |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Naijiria |
Ẹ̀kọ́ | ede geesi, University of Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | UniUniversity of Nigeria |
Iṣẹ́ | osere ati akewi |
Itan Ibeerepepe aiye re
àtúnṣeWon bi Ada si ipinle Enugu. Baba re je omo eya Igbo, iya re si je omo ile Amerika.[1] Ada dagba ni orile ede Naijiria sugbon oun ati awon molebi re lo si ilu Amerika nigba ti ogun biafra bere, won si pada leyin ti ogun na pari.[2] O je omo ise Chinua Achebe, o si gboye bachelor's degree ninu ede geesi ni ile eko giga ti University of Nigeria ni odun 1981. Leyin odun die, o beere si ni ya aworan si ara aso, awon ise ti o ti se wa ni Newark Museum of Art.[3][4] Udechukwu je ikan laarin awon obinrin ti o wa ni egbe Nsukka.[5]
Ada Udechukwu je gbajumo akowe ati akewi. o ti ko awon iwe bii Woman ati Me[6] eyi ti ile ise Boomerang Press gbe jade. Iwe ranpe (Night Bus) ti o ko wa ni oju iwe iroyin ti The Atlantic.
Awon Itokasi
àtúnṣe- ↑ "The Poetics of Line". africa.si.edu. Retrieved 2020-05-28.
- ↑ "TOP 10 MOST FAMOUS NIGERIANS IN ART, MUSIC AND SCULPTURE". www.traveldigest.com.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-28.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Search Our Collection | Newark Museum". www.newarkmuseumart.org. Retrieved 2020-03-07.
- ↑ Cotter (15 August 2013). "Nigeria in the Middle of Newark". The New York Times. https://www.nytimes.com/2013/08/16/arts/design/some-of-simon-ottenbergs-gifts-in-the-art-of-translation.html.
- ↑ "The Poetics of Line". africa.si.edu. Retrieved 2020-03-07.
- ↑ Udechukwu, Ada Obi, 1960- (1993). Woman, me. Bayreuth, Germany: Boomerang Press. ISBN 3-9802212-7-X. OCLC 28832296.