Adaku Okoroafor jẹ àgbàbọọlu lóbinrin orilẹ ede Naigiria ti a bini 18, óṣu November ọdun 1974 nibi ti o ti jẹ elere fun National Awọn óbinrin agbabọọlu orilẹ ede Naigiria. Arabinrin na jẹ ara team FIFA Awọn óbinrin agbaye Cup ni ọdun 1991 ati 1995[1].

Adaku Okoroafor
Personal information
Ọjọ́ ìbí18 Oṣù Kọkànlá 1974 (1974-11-18) (ọmọ ọdún 50)
Ibi ọjọ́ibíUguta
Ìga1.60m
Playing positionForward
National team
Nigeria women's national football team
† Appearances (Goals).
‡ National team caps and goals correct as of 5 June 1995 (before the 1995 FIFA Women's World Cup)

Aṣeyọri

àtúnṣe
  • Adaku kopa ninu 1995 óbinrin agbaye Cup ni ilu sweden ti o si di eni ti aye mọ[2]

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.celebsagewiki.com/adaku-okoroafor
  2. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-04-09. Retrieved 2022-05-23.