Adam A Zango
Adam A Zango tí wọ́n tún mọ̀ sí Gwaska, jẹ́ òṣèré,olùgbéré-jáde, adarí eré, olùkọ̀tàn, olórin ọmọ ẹ̀yà Hausa ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni wọ́n gbà wípé ó jẹ́ ẹni tó lààmì-laaka jùlọ ní agb Kannywood. Ní ọdún 2019, ó júwe ara rẹ̀ gègẹ́ bí ẹni tí ó nípa jùlọ ní ilẹ̀ Hausa. Púpọ̀ nínú àwọn adarí eré ní agba Kannyeood ni wọ́n ń gbóríyìn fún látàrí bí ó ṣe lè kópa dáradára ní inú ipa èyíkéyí tí wọ́n bá fún wípé kí ó ṣe. Adamu Zsngo ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí ti Ali Nuhu náà ní agbo àwọn òṣèré Kannywood. [1]
Adam a zango | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Adamu Abdullahi Zango 1 Oṣù Kẹjọ 1985 Zangon Kataf, Kàdúná, |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Òṣèré orí-ìtàgé, Olùgbéré-jáde Ọ̀kọrin àti oníjó. |
Net worth | ₦100million Naira |
Olólùfẹ́ | Safiya chalawa |
Àwọn ọmọ | Haidar A Zango |
Awards | Best Actor |
Ìgbà èwe àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Adam Abdullahi Zango ní inú oṣù Kẹwàá ọdún 1985, ní Agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Zango ní Ìpínlẹ̀ Kádúná. Babá rẹ̀ ni Mallam Abdullahi Adam. Zango kò lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga kankan, amọ́ ó lérò wípé ìkẹ́kọ̀ọ́ ju kí a kó ìwé-ẹ̀rí aọ́wọ́ lọ, amọ́ ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní àárín ọdún 1989–1995, tí ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gurama ní àárí ọdún 1996–2001.Àdàkọ:Cn
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeAdam Zango ti bẹ̀rẹ̀ sí ń kọrín nígbà tí ó ti wà ní ilé-ẹ̀kọ́ girama . Òun náà ló ma ń ṣojú ilé-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní inú ìdíje eré ati orin ní abẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ rẹ̀. Zango dara pọ̀ mọ́ Kanywood ní ọdún 2001gẹ́gẹ́ akọrin, amọ́ tí ó lo ànfaní yí láti bẹ̀rẹ̀ sí ń kópa nínú àeọn eré orí-ìtàgé gbogbo. Ó ti kópa nínú eré tí ó ti tó ọgọ́rùn ún ṣáájú kí ó tó di àgbà ọ̀jẹ̀ òṣèré ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó ti gba amì-ẹ̀yẹ Africa Movie Award in London, ní ìlú UK.
Bí ó ṣe lọ sí ẹ̀wọ̀n
àtúnṣeWọ́n fi Adam A. Zango sí ọgbà ẹ̀wọ̀n fún bí ó ṣe lu òfin ìkànìàn ní ti ọdún 2007 látàrí orin rẹ̀ tí ó gbé jáde lórí ètò ìkànìyàn tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ Bahaushiya.[2]
Ìtọrẹ Àánú rẹ̀
àtúnṣeNí inú oṣù Kẹwàá ọdún 2019, Adam fún àwọn ọmọ aláìníyá ní iye tí ó tó 47 million láti lè jẹ́ kí wọ́n tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ wọn.[3]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
àtúnṣe
Eré | Ọdún |
---|---|
Ya Ya na | ND |
Yar Agadez | 2011 |
Adamsi | 2011 |
Addini ko Al 'Ada | 2011 |
Adon Gari | 2011 |
Ahlul Kitab | 2011 |
Alkawari na | 2011 |
Albashi (The Salary) | 2002 |
Andamali | 2013 |
Ango da Amarya | ND |
Artabu | 2009 |
Aska Tara | ND |
Auren Tagwaye | ND |
Baban Sadik | 2012 |
Babban Yaro | 2011 |
Balaraba | 2010 |
Basaja | 2013 |
Bayan Rai | 2014 |
Bita Zai Zai | ND |
Dajin So | ND |
Dan Almajiri | ND |
Dare | 2015 |
Dijangala | 2008 |
Duniya Budurwar Wawa | ND |
Dutsen Gulbi | 2013 |
Farar Saka | ND |
Fataken Dare | ND |
Ga Duhu Ga Haske | 2010 |
Ga Fili Ga Mai Doki | ND |
Gaba da Gabanta | 2013 |
Gambiza | ND |
Gamdakatar | ND |
Gwamnati | 2003 |
Gwanaye | 2003 |
Gwaska | 2016 |
Hadizalo | ND |
Hindu | 2014 |
Hisabi | 2017 |
Hubbi | 2012 |
Ijaabaah | ND |
Jamila | 2016 |
Kaddara Ko Fansa | 2014 |
Kama da Wane | 2014 |
Kare Jini | ND |
Kolo | ND |
Kundin Tsari | ND |
Laifin Dadi | 2010 |
Larai | ND |
Madugu | ND |
Masu Aji | ND |
Mata ko Ya | 2015 |
Matsayin So | ND |
Mazan Fama | ND |
Matsayin So | ND |
Mazan Fama | 2015 |
Mukaddari | ND |
Murmushin Alkawari | ND |
Mutallab | 2011 |
Nai Maka Rana | ND |
Namamajo | ND |
Nas | 2013 |
Ni Da Ke Mun Dace | 2013 |
Najeriya Da Nijar | 2012 |
Nusaiba | ND |
Rabin Jiki | 2011 |
Rai A Kwalba | ND |
Rai Dai | 2012 |
Rawar Gani | ND |
Rintsin Kauna | ND |
Rumana | 2017 |
Ruwan Ido | ND |
Ruwan Jakara | ND |
Sai Wata Rana | 2010 |
Salma | ND |
Shahuda | 2012 |
Siyayya Da Shakuwa | 2014 |
Sayayyar Facebook | 2013 |
Tarkon Kauna | ND |
Tsangaya | ND |
Ummi da Adnan | 2011 |
Walijam | 2010 |
Wata Rayuwa | 2013 |
Ya Salam | ND |
Zanen Dutse | ND |
Zarar Bunu | 2011 |
Zatona | ND |
Zeenat | 2014 |
Zo Mu Zauna | ND |
Zulumi | 2017 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1 minute read (2018-05-06). "Brief history of Prince Adam A Zango and his collection of photos –". Gobirmob.com. Archived from the original on 2018-02-18. Retrieved 2019-09-04.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 24 February 2013. Retrieved 12 May 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ A Zango ya raba guraben karatu ga fadar sarkin zazzau Legit Hausa
- ↑ Flowalk (2017-03-25). "The Biography Of Adam A. Zango [Age, Life Profile & Net Worth]". 360post.wordpress.com. Archived from the original on 2019-05-12. Retrieved 2019-09-04.