Adam Riess
(Àtúnjúwe láti Adam Guy Riess)
Adam Guy Riess (ojoibi December 1969, Washington, D.C.) je asefisiksi-irawo ara Amerika ni Johns Hopkins University ati ni Space Telescope Science Institute to gbajumo fun iwadi re fun lilo supernovae bi Cosmological Probes.
Adam Guy Riess | |
---|---|
Adam Riess receiving the Shaw Prize in astronomy in 2006 for the discovery of cosmic acceleration | |
Ìbí | Oṣù Kejìlá 1969 (ọmọ ọdún 54) Washington, D.C., U.S. |
Ibùgbé | United States |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | American |
Pápá | Physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Johns Hopkins University / Space Telescope Science Institute |
Ibi ẹ̀kọ́ | Massachusetts Institute of Technology, Harvard University |
Ó gbajúmọ̀ fún | Accelerating universe / Dark energy |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Shaw Prize in Astronomy (2006) Nobel Prize in Physics (2011) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣeWikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Adam Riess |