Adan Mohammed
Adan Abdulla Mohammed jẹ́ gbajúgbajà òṣìṣẹ́ ilé-ìfowópamọ́ ti ìlú Kenya àti oníṣòwò. Ó fìgbà kan sìn gẹ́gẹ́ bí i adarí àgbà ti Barclays Bank ní Ìwọ̀-oòrùn ti àti West Africa.[1]
Adan Mohammed | |
---|---|
Àdàkọ:Lang-so Lárúbáwá: عدن محمد | |
Cabinet Secretary for Industrialization and Enterprise Development | |
In office 15 May 2013 – 14 January 2020 | |
Ààrẹ | Uhuru Kenyatta |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | December 1, 1963 (ọmọ ọdún 61–62) El Wak, North Eastern Province |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Kenyan |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Nafisa |
Àwọn ọmọ | 5 |
Alma mater | University of Nairobi (BCom) Harvard Business School (MBA) |
Profession | Chartered Accountant (ACA) |
Ethnicity | Somali |
Positions | MD, Barclays Kenya (2002-12) |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Omino, Brian (15 May 2013). "Cabinet Secretaries Take Oath of Office". The Star. http://allafrica.com/stories/201305160844.html. Retrieved 16 May 2013.