Adanna Nwaneri

Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà

Adanna Nwaneri jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini ọjọ 31, óṣu August ni ọdun 1975. Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi defender fun team awọn obinrin apapọ ilẹ naigiria lori bọọlu[1][2][3].

Adanna Nwaneri
Personal information
Ọjọ́ ìbí31 Oṣù Kẹjọ 1975 (1975-08-31) (ọmọ ọdún 49)
Playing positionDefender
National team
Nigeria women's national football team
† Appearances (Goals).
‡ National team caps and goals correct as of 19 June 1999 (before the 1999 FIFA Women's World Cup)

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Adanna wa lara awọn agbabọọlu ti o kopa ninu FIFA Cup awọn obinrin agbaye ni ọdun 1999[4][5].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.playmakerstats.com/player.php?id=182370&edicao_id=2150
  2. https://fbref.com/en/players/83e778fc/Adanna-Nwaneri
  3. https://www.eurosport.com/football/adanna-gloria-nwaneri_prs414906/person.shtml
  4. https://ng.soccerway.com/players/adanna-nwaneri/291454/
  5. https://www.kick442.com/adanna-nwaneri-reminiscences-playing-days-says-falcons-can-break-quarter-final-bus-stop/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]