Adaora Elonu
Agbábọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Adaora Elonu jẹ ọkan lara agbabọọlu inu agbọn obinrin ninu Naigiria ti a bini 28, oṣu April ni ọdun 1990 jẹ aburo fun Àkọṣẹmọṣẹ agbààlọlu lobinrin inu agbọn tì orukọ rẹ n jẹ Chinemelu Elonu. Adaora ni asiko yi gbààbọọlu fun CB Avienda[1].
CB Avenida | |
---|---|
Position | Forward |
League | Liga Femenina de Baloncesto |
Personal information | |
Born | 28 Oṣù Kẹrin 1990 Houston, Texas, United States |
Nationality | Nigerian / American |
Listed height | 6 ft 1 in (1.85 m) |
Listed weight | 165 lb (75 kg) |
Career information | |
High school | Alief Elsik High School |
College | Texas A&M Aggies women's basketball |
NBA draft | 2012 / Undrafted |
Pro playing career | 2012–present |
Career history | |
2012–2013 | Hapoel Galil Elyon |
2013–2014 | Beroil–Ciudad de Burgos |
2014–2016 | CB Conquero |
2016–2018 | CB Avenida |
2018 | Atlanta Dream |
2019–2021 | Uni Girona CB |
2021–2022 | Nadezhda Orenburg |
2022–present | CB Avenida |
Career highlights and awards | |
|
Aṣeyọri
àtúnṣe- Adaora ti gba inu agbọn fun college ni Texas A&M, nibi ti arabinrin naa ti jẹ ninu NCAA championship ni ọdun 2011[2].
- Adaora ti fi igba kan ko awọn ọdọmọbinrin jọ fun ọjọ kan lori ọrọ inu agbọn gẹgẹbi camp ni ipinlẹ Enugu lati fi ṣe àwari talent làrin awọn ọdọ ni orilẹ ede. Atipe Wọn tì fì arabinrin naa jẹ MVP ninu Idije bọọlu inu àgbọn[3].
Itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://www.topinfoguide.com/wikipedia/adaora-elonus-biography-fact-career-awards-net-worth-and-life-story-081023[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ https://www.zgr.net/en/people/adaora-elonu/amp
- ↑ https://www.fiba.basketball/news/reigning-womens-afrobasket-mvp-adaora-elonu-commits-to-nurturing-new-talents-in-nigeria